Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Èwo o, ọwọ́ mi ree, mi o sa kiri mọ
Gbajumọ olorin takasufee nni, Portable lo lọ fara kalẹ ni agọ ọlọpaa to wa lekoo
Agbẹnusọ ọlọpaa Eko, Benjamin Hundeyin lo fidi ọrọ naa mulẹ fawọn akọroyin sọ pe
Awọn ti kan si ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ogun lati wa mu un
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Muso muso muso!
Emi lo de to n dawọ idunnu bayii
Ikede ajọ NBS ma ni pe ọwọngogo to gbẹnu soke ni Naijiria ma ti ja walẹ pẹlu ida mẹwaa
O jẹ ma i tii jẹ inu rẹ dun ju nitori pe wọn ni ko tumọ si pe owo ọja ma walẹ rara
Ewo lo tun n sọ yii?
Ẹkunrẹrẹ alaye nipa ikede naa wa loju opo bbcnews.com/yoruba
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Níṣe ni ìdùnnú ṣubú layọ̀ fún àgbà òṣèré nnì Abigail Oladeji tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Iya Niwe
nígbà tí Oriyomi Hamzat ṣilé tuntun fun-un n'Ibadan lọjọ Iṣẹgun
Iya Niwe to n ṣomi gbere gbere loju pẹlu idunnu
Ni oun ko mọ bi oun yoo ṣe dupẹ fun oore nla naa
