You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
World Radio Day: Àwọn òṣìṣẹ́ rédíò ní àwọn ń pa ìsòro àwọn mọ́ra ni láti mú inú aráàlú dùn
Loni tii se Ọjọbọ, ọjọ Kẹtala osu keji tun ni ayajọ miran fun eto igbohunsafẹfẹ lori redio tun ko.
Idi si niyi ti BBC Yoruba fi jade sita lati ba awọn ilumọọka agbohunsafẹfẹ sọrọ nipa iriri wọn lknu isẹ ati awọn ipenija to n koju wọn.
Olanrewaju Adewusi, Titilayo Akinsola ati Abiodun Adewole salaye pe lootọ ni isẹ igbohunsafẹfẹ lori redio maa n mu iyi, apọnle ati ẹwa ba awọn, amọ isẹ la ri, ọwọ n kako lasan ni.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Wọn fi kun pe awọn saba maa n pà ipenija tawọn ba n koju mọra lasiko ti awsn ba wa lori afẹfẹ ni, lọna ati mu ayọ ati idunnu ba awọn eeyan to n gbọ awọn.
Wọn wa n gbadura pe ki Ọlọrun fi owo ti isẹ igbohunsafẹfẹ nidi, ko ma jẹ pe awsn yoo kan gbe orukọ lori ni.
- Ìsinmi oṣù mẹ́fà lẹ́yìn ìbímọ yóò túbọ̀ mú àdínkù bá ikú mọ wẹ́wẹ́ - Àwọn Obìnrin Ekiti
- Àìsí ẹ̀rọ ìgbàlódé fún bàálù láti bà ní Nàíjíríà, mú káwọn bàálù láti òkè òkun lọ bà sí Ghana
- Ẹ san ₦200,000 fún Sowore lórí bí ẹ ṣe ń fi ẹjọ́ falẹ̀ - Iléẹjọ́ pàṣẹ fún ìjọba
- Buhari, èyí to fí ogún ọdún pilẹ̀ wèrè lórí ètò ààbò Nàìjíríà tó gẹ́ - Bishop Kukah