Àwọn àwòrán mánigbàgbé àsìkò Yemi Osinbajo lórí ipo ìgbákejì ààrẹ Nàìjíríà

Ọdun mẹjọ ti Igbakeji aarẹ Yemi Osinbajo lo jẹ eyi ti ọpọ ko ni gbagbe.Awọn aworan reeti yoo maa jẹ iranti.

Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Ayanyemi Osinbajo yin ti de!
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Awọn obinrin ko fi ọrọ Osinbajo ṣere rara
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Nibikibi to ba lọ, awọn ọmọde fẹran rẹ pupọ
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Awọn ẹsọ rẹ yoo sinmi diẹ ni bayii to ṣetan lati pari saa rẹ nijọba.
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Awọn oṣere ati akọrin Naijiria ko ni yara gbagbe Buoda Yemi onifaaji
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Aworan yi nigba to lu sita mu ọpọ eeyan maa beree pe bawo ni baba yi ṣe jẹ si igbakeji aarẹ
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo ati Iyawo rẹ

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Igbakeji aarẹ kii tiju lati se afihan ifẹ to ni si iyawo rẹ Dolapo
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo ati Mama rẹ

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Iya ni Wura iyebiye!
Aworan Igbakeji Aarẹ Yemi Osinbajo ati Olamide Badoo

Oríṣun àwòrán, Facebook/Yemi Osinbajo

Àkọlé àwòrán, Iru amọran wo lẹ ro pe igbakeji Aarẹ n fun Olamide Badoo?