You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ajagbe Toriola Oyewo ògbóǹtarìgì agbẹjọ́rò SAN ti jáde láyé lẹni ọdún mọ́kànlélàádọ̀rún ùn
Olùkọ́ ìmọ̀ òfin, ọ̀jọ̀gbọ́n Toriola Ajagbe Oyewo dágbére fáyé lẹ́ni ọdun mọ́kànléláàdọ́ruún
Olùkọ́ ìmọ̀ òfin, ọ̀jọ̀gbọ́n Toriola Ajagbe Oyewo ti kí dúnìyàn pé ó dìgbà.
Ní ọdún tó kọjá ni ọ̀jọ̀gbọ́n Toriola Ajagbe Oyewo gba oyè Amòfin àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà (SAN).
- Àjọ ìṣọ̀kan ilẹ̀ Àdúláwọ̀ fòfin de Burkina Faso lórí ìdìtẹ̀gbàjọba
- ASUU Fasiti Obafemi Awolowo fárígá, ìyansẹ́lódì tẹ̀síwájú lórí pínpín owó àjemọ́n;ú àwon Olùkọ́
- 'Orí Facebook ni mo ti kọ́ nípa òògùn owó táà gé orí Sofiat fún ní Abeokuta'
- Aminu Tambuwal fi èròńgbà rẹ̀ láti díje dupò aàrẹ̀ Nàìjíríà
- Tí òògùn owó bá wà nínú Ifa ni, n kò bá ti kọ́ ilé ńlá fún ara mi- Babaláwo
- U.S. yóò máa fún àwọn ọmo Nàìjíríà kan ní físà ìwé ìrìnnà láì ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò
Ọjọ̀gbọ́n Toriola Ajagbe Oyewo dágbéré fáyé lẹ́yìn to wa nibudo itọju nla ní ilé ìwòsàn UCH, Ibadan.
Mọ̀lẹ́bí olóògbé ní bí ọjọ́ díẹ̀ ni ọ̀jọ̀gbọ́n Oyewo ní ìjàmbá ọkọ̀ ní ọ̀nà ìlú Owo.