You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Mompha: Iléẹjọ́ ní kí EFCC gbẹ́sẹ̀ lé aago àti awò ojú márùn-ún rẹ̀ pẹ̀lú fóònù iphone 8 kan
Ileẹjọ giga kan nipinlẹ Eko ti pasẹ pe ki ajọ EFCC gbẹsẹle awọn dukia ẹsọ ara olowo iyebiye to jẹ ti Ismaila Mustapha, ti ọpọ eeyan mọ si Mompha.
Awọn ẹsọ ara naa ni awo oju marun olowo nla, aago olowo iyebiye marun ati foonu ibaraẹnisọrọ iphone 8.
Awọn dukia olowo iyebiye tii ni ajọ EFCC gba lọwọ Mompha losu Kẹwa ọdun 2019 nigba ti wọn mu ni papakọ ofurufu Nnamdi Azikwe to wa nilu Abuja.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Àlàyé rèé lórí ohun tí ojú mi rí ní àhámọ́ - Chiwetalu Agu
- Agbébọn jí ìbejì ọba gbé àti èèyàn mẹta míì ní Kwara
- Bimbo Oshin ṣàlàyé ọ̀rọ̀ ìkẹyìn tí ọkọ rẹ̀ sọ fun un kó tó kú
- Wo àwọn ohun mẹ́jọ́ tí àwọn olólùfẹ́ gbọ̀dọ̀ ṣe lẹ́yìn ìbálòpọ̀
- Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa Ọ̀jọ̀gbọ́n Oyebode Adebowale, gíwá tuntun ní fásitì Ibadan
- Godwin ṣá bàbá rẹ̀ ládá pa nítorí orí adìyẹ, Ó ní...
- Ẹ wo bí arákùnrin kan ṣe fi ọrún àti ọfà pa èèyàn márún ún
- "Olórí ọmọ ogun Islamic State ní Ìwọ̀ Oòrùn Afrika, ISWAP ti jáde láyé"
- Sàdáńkátà! Ẹ̀yin ẹ̀létò ààbò, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ yín fún ìkọlù sí ilé Sunday Igboho - Ààrẹ Buhari
- Àwọn afurasí gbin ǹkan olóró abúgbàmù sí ṣọ́ọ̀ṣì bàbá Wike, ọwọ́ pálábá wọ́n ségi!
Adajọ Lewis Allagoa lo pasẹ bẹẹ lẹyin to gbọ ẹbẹ agbẹjọro fun EFCC, Chinenye Ugwoke, to si ni asẹ naa yoo mulẹ titi ti EFCC yoo fi pari iwadii wọn lori Mompha ati ileesẹ rẹ, Ismalob Global Investment Ltd.
Mompha, ẹni tii se gbajumọ lori ayelujara lo ti n foju wina ẹsun onikoko mẹrinla to nii se pẹlu gbigbe owo tuulu lọ soke okun lọdun 2019, eyi to to biliọnu mẹtalelọgbọn o din diẹ (N32.9 bn).
Awọn eroja olowo tuulu mọkọọkanla naa ni iwọnyii:
Awo oju marun ti wọn mọ idamọ wọn si Tomford - TF586; Cartier - B17C76B; Montblanc - MB0045S ati Louis Vuitton- Z1186E.
Awọn aago ọwọ marun naa ni orukọ wọn n jẹ Rolex Oyster Perpetual; Audemars Piguet; Audemars Piguet- J46220; XY Hublot - 1321920 ati XY Hublot- 924206.
Nọmba idamọ ẹrọ ibaraẹnisọrọ iPhone 8 naa ni C8PVF1LKJC6C.
Agbẹjọro ajọ EFCC bẹ ileẹjọ pe ko pasẹ ki awọn gbẹsẹle awọn eroja yii lọna ati da olujẹjọ lọwọ kọ ko maa baa tọwọ bọ awọn eroja ọhun, eyi ti awọn fura si pe o fi owo to ri lọna eru ko jọ.
Wo aṣòfin àpapọ̀ tó fẹ́ káwọn káfíńtà àti dẹ́rẹ́ba ọlọ́kọ̀ èrò má san owó orí, Ó ní owó kékéré kó ni wọ́n rí
Ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú ṣòfin kan l'Abuja láti ìpínlẹ̀ Osun ti ni àwọn olókoòwò kéékèkè tó fi mọ́n àwọn káfíntà àti àwọn dẹ́rẹ́bà ọkọ ìgboro lo gbọdọ̀ máa san owó orí lórí òwò wọn.
Fakeye Olufemi, ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress to n sojú Boluwaduro/Ifedayo/ Ila ni ìpínlẹ̀ Osun ló sọ èyí níwájú ilé aṣòfin apapọ.
Òfin isúná ọdun 2020 yọ gbogbo àwọn ilé iṣẹ́ kéékèkè ti owó ti wọ́n pa ko ju mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dọ́gbọ́n lọ lọ́dun sílẹ̀ nínú sísan owó orí.
- Odunlade, a fún ọ lọ́jọ́ méje, yọ sinimá tó ń fi ẹlẹ́hàá ṣe yẹ̀yẹ́ kúró lórí ayélujára - Ẹgbẹ́ THURIST
- Àgùnbánirọ̀ yóò kojú Boko Haram, agbébọn pẹ̀lú ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ológun - Fayemi
- Wo bí àṣà ìbálé lálẹ́ ìgbeyàwó ṣe ń dọdẹ àwọn obìnrin òde òní kiri
- "Ẹ tètè gbé Sunday Igboho lọ fún ìtọ̀jú lókè òkun, kó tó pẹ́ jù"
Olufemi, lásíkò to n dásí ètò isúna ọdún 2022 lásìkò ìjọkó ilé, ló tí ni èyí yóò túbọ mu ki owọ iṣúná rú gọ́gọ́ si fún ìjọba àpapọ̀.
Bákan náà lo fi kú pé, òun ni ifẹ̀ láti sọ fún àwọn ìgbìmọ̀ aláṣẹ ijọba pé tí wọ́n bá n pinu láti yáwó fún iṣẹ́ òde kan , ki wọ́n yá owó náà nínú oṣù kíní tàbí ikèjì sí ikẹta, kìí ṣe ki wọ́n má yáwó ní osù kẹrin ọdún nítorí kò lé rọrùn láti tún máá gbé ètò ìṣúná pàdá wá sí iwájú ilé fún atúntò.
" Mo gbọ́ pé, wọ́n ti buwọlu owó sáà méjì, bẹ́ẹ̀ sáà tó kẹ́yìn nínú ọdún ni a wa. Èyí ba gbogbo gbogbo wàhálà ti a ti n ṣe láti ẹ̀yin wá láti ri dáju pé, ètò iṣún ti ààrẹ gbé wá si iwájú ilé kọja.
" Mó n ri bi owó ti ìjọba n pa wọle ṣe n dínkù lójoojúmọ́, sùgbọ́n mo mọ̀ pé gbogbo ènìyàn ló n sa owó orí nígbà náà, yálà o jẹ́ káfíntà, abí awakọ èrò, ohun yó[wù kí o ma ṣe gẹ́gk bi iṣẹ́ òòjọ́.
" O ṣe pàtàkì kí ètò owó orí wá ní Nàìjíríà láti fi aayè gba gbogbo ènìyàn láti san owó orí, Jáde lọ kí o lọ bèrè lọ́wa àwọn ènìyàn níta idá ọgọ́rin sí àádọ́rùn tó n ṣe iṣẹ́ ara wọn wọn kìí san owó orí.
Ẹ̀wẹ̀, ti a bá n gbọ́ pé FIRS ń fẹ ètò owó orí gbígbà sí, kíló dé tí wan ko wá ọ̀nà láti mú kí àwọn ènìyàn yìí máa san owó, yálà ò ń ṣiṣẹ́ káfíntà, awakọ̀, tàbi oun ta ìrẹ̀si ninú ọjà.
Àwọn ènìyàn yìí n rí bẹ̀nbẹ owọ, sùgbọ́n wọn kìí san kabọ̀.