You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Senato Francis Fadahunsi sọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lórí kíkó ẹ̀rù wọlé láti ẹnubodè Nàìjíríà báyìí
Lai jẹ́ pe wọ́n yọ ologun to n dari ileeṣẹ aṣọbode ki wọn si fi ẹni to kọṣẹmọṣẹ sii, nkan ko le rọgbọ- Senato Fadahunsi Francis.
Senatọ Francis Adenigba Fadahunsi to n ṣoju ẹkun Ilesa nile igbimọ asofin agba ni Abuja ba BBC Yoruba sọrọ lori ipo ti ile iṣẹ aṣobode Naijiria wa lasiko yii.
O mẹnuba ohun ti o le ṣo gẹgẹ bi ẹni to ti ṣe iṣẹ aṣọbode fun ọpọlọpọ ọdun pẹlu iriri, o sọ nipa ọna abayọ si iṣoro ibẹ gẹgẹ bii alaga igbimọ to n ri si ọrọ ẹnubode Naijiria nile igbimọ Asofin.
Fadahunsi ni ọwọ iyawo awọn aṣọbode ko mọ nipa kiko ẹru wọle lati ilẹ okeere.
Koda, o ni kii ṣe bi wọn ṣe kọ wọn ni won n ṣiṣẹ mọ.
Wo ohun tó yẹ kí ará ìlú ṣe tí 'Custom' bá ṣèṣì pa wọ́n- Senatọ Fadahunsi
- Àwọn Òṣèré fíìmù Yorùbá tẹ́ ò ro tó tí jápaa lọ ìlú Òyìnbó rèé
- Kí ló lè mú kí ará ìlú fárígá pátápátá nítorí pé kò sí iná mọ̀nàmọ̀nà?
- Ẹ wo Ajá tó ń gbọ́ òórùn àìsàn ibà, ẹja tí a kò gbọdọ̀ pa àti ọọ̀nì tó ń gbọ́ àdúrà ní Ìbàdàn
- Mọ̀ síi nípa iṣẹ́ tí Àjẹ́ ń ṣe ní China, Japan àti gbogbo àgbáyé, kò síbi tí wọn kò sí- Abiodun Fatomilola
- Wàhálà bẹ́ sílẹ̀ nílé aṣòfin, káńsẹ́lọ̀ obìnrin ní alága ìjọba ìbílẹ̀ ló pàṣẹ pé káwọn jàndùkú fa aṣọ òun ya.
- Ojú wa rí tó lásìkò tì a wà ní àhámọ́ ajínigbé, koríko la jẹ fún ọjọ́ 52
- Àwọn olọ́kadà ti gba àwọn ìyàwó wa tán nítorí a kò lówó lọ́wọ́- Àwọn òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì ni Benue
Nigba ti BBC kan si ileeṣẹ aṣọbode Naijiria lati fesi si awọn ẹsun yii, wọn ni wọn maa ṣe iwadii ki wọn si kan si BBC pada.
Sugbon titi di asiko yii, ileeṣẹ aṣọbode Naijiria ko tii kan si BBC pada.
- Ṣé lóòtọ́ ni ìjọba orílẹ̀-èdè Benin ti gba àbọ̀dè lórí ẹjọ́ sunday Igboho?
- Láti ìgbà ti mo ti fún ọkọ mi ni ẹ̀bùn ni ìfẹ́ wa ti pọ̀ síi; ẹ̀yin obìnrin, ẹ ni iṣẹ́ lọ́wọ́ láti lè ni òmìnira láti máa ra ẹ̀bùn
- Láti ọdún mẹ́rin sẹ́yìn ìjọba Mozambiqe ni àwọn kò mọ agbésùmọ̀mí níbẹ̀
- Kò ní ìyá kò ní bàbá ni ọmọ tí ògiri kíláàsì wó pa
- Mọ̀ sií i nípa Oba Yesufu Asanike , Olubadan tí kìí fi ọ̀rọ̀ sí abẹ́ ahọ́n sọ kódà níwájú sọ́jà
- Opó ni Ìyá mi, kẹ̀kẹ́ ti mò ń gùn fi kiri ẹja ń jẹ́ kí a tà síi- Abdusalam ẹlẹ́ja yiyan