You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Hadiza, ìyàwó Ààrẹ Shagari jáde láyé lẹ́ni ọdún 80
Hadiza Shagari to jẹ iyawo aarẹ orilẹede Naijiria nigbakan ri, Shehu Usman Aliyu Shagari ti jade laye.
Iroyin n sọ pe arun covid-19 lo ṣekupa Iyawo aarẹ alagbada lorilẹede Naijiria nigbakan ri naa lọjọbọ, ọjọ kejila oṣu kẹjs ọdun 2021 nilu Abuja.
- Apostle Suleman lo ọlọ́pàá láti fi ìyà jẹ oníbàárà mi, ó fi sí àtìmọ́lé torí ọ̀rọ̀ tó sọ - Amòfin
- Ẹ̀dà Delta Variant COVID-19 ń gbèrú síi ní Nàìjíríà, ìjọba àpapọ̀ ra abẹ́rẹ́ àjẹsára 176,000
- Ẹ̀rú ní ìran Bode George, kò ní orírun nílẹ̀ Yorubá, ọ̀rọ̀ rẹ̀ kò yà wá lẹ́nu - YWG
- Àwọn aráàlú Igboho bẹ̀rẹ̀ ìjà ẹ̀mí fún ìdáǹdè Sunday Igboho
Atẹjade kan eyi ti ajagunfẹyinti Muhammad Bala Shagari lo fi iroyin iku rẹ mulẹ.
Nnkan bii agogo mẹta oru ni arabinrin Hadiza jade laye nileewosan Gwagwalada Isolation Center nilu Abuja.