Sunday Igboho in Benin republic: Ẹ máṣe dágunlá, nǹkan àmúṣagbára ìṣẹ̀mbáyé ilẹ̀ Yorùbá ṣì wà bíi ti àtijọ́ -Ààrẹ ọ̀nà kakanfò Gani Adams
"Leṣẹbọ le ṣoogun, baa ti waye paari laari o".
Ọrọ ti Iba Gani Adams, Aarẹ Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba fi ṣide ọrọ lori ifọrọwerọ rẹ pẹlu BBC News Yoruba lori boya lootọ nnkan agbara ṣi wa.
Iba Gani Adams ni lootọ awọn nnkan ti a n ri ni ayika wa lee maa mu iyemeji wa ori boya agbara nbẹ tabi booya oogun wa, sibẹ awọn ọmọ Yoruba ṣi nilo lati gbagbọ ninu iṣẹṣe wọn.
O ni kii ṣe pe ko si ohun amuṣagbara Yoruba mọ, ati pe koda nigba iwaṣẹ awọn alagbara n ṣubu pẹlu.
- Wọ́n ti fi ẹ̀sùn míì kan Sunday Igboho ní ìlú Benin! - Agbẹ́jọ́rò Igboho
- Baba Ijesha: Wọ́n gbé ọmọdé kan wá sílé ẹjọ́ kó wá jẹ́rìí sí ẹ̀sùn Baba Ijesha àti Princess
- Ọmọ Ìjọ Deeper Life Pọ́ńbélé ni ìyà mi àti bàbá mi, mo sì dàgbà síbẹ̀ àmọ́ bíbọ Èṣù ọ̀dàrà lọ́nà tó tọ́ -
- Ẹ gbé Sunday Igboho kúrò láhàmọ́ ọlọ́pàá wá sí ibi ìpamọ́ mìí ní Cotonou títí tí... - Adájọ́
- 'Ìjìyà Ọlọ́run n'ìjọba Buhari' - Sẹ́nétọ̀ Okunrounmu
- Pẹ̀lú omijé lójú làwọn òbí akẹ́kọ̀ọ́ 28 Bethel Baptist táwọn ajínigbé tú sílẹ̀ fi pàdé ọmọ wọn

