You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
India Corona scourge: Àlàyé rèé lórí ohun tó ń fa bí kòkòrò COVID-19 India ṣe búrẹ̀kẹ̀
Lẹnu lọọlọ yii ni okiki gbalẹ pe ọwọja arun Coronavirus ti legba kan ju ọrin lọ ni orilẹede India.
Laarin osu kan, o si le ni miliọnu marun eeyan to ti lugbadi kokoro arun naa, idi si ree ti ileesẹ BBC se tanna wadi ohun to fa itankalẹ arun naa lẹnu lọọlọ yii ni India.
Iwadii BBC ti wa fidi rẹ mulẹ pe bi awọn eeyan se seraro lori awọn ilana to n dena itankalẹ arun Covid-19 lo fa sababi.
Bakan naa la tun fidi rẹ mulẹ pe oniruuru ẹya arun Coronavirus lo ti su yọ ni India, to si rọrun fun lati tete ran ẹlomiran.
Iwadii tun fidi rẹ mulẹ pe ẹya arun naa to wa lati ilẹ United Kingdom UK lo pọ ju awọn ẹya arun Covid-19 miran lọ.
Koda, aaye ko fẹ si mọ lati sin awọn oku to n jade laye lati ipasẹ arun naa bayii.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ikú tó fẹ́ pa Opeyemi Ayeola ṣí i ní fìlà, ló bá ń kọrin ẹ fọ̀rọ̀ mi kọ́gbọ́n
- Nǹkan pàtàkì mẹ́wàá tó yẹ kí o mọ̀ nípa Salawa Abeni bí ó ṣe pé ọgọ́ta ọdún.
- Ayé ń pè wá ní 'Yeyebrity' torí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha, nǹkan bà wá lágbo tíátà Yoruba"
- Wo àwọn olówó ayé tí ìgbéyàwó wọn ti wó lulẹ̀
- Ìyá àláwo tó di àjíhìnrere òjijì fi àwọn òrìṣà rẹ̀ ṣe ẹlẹ́yà
- Eré orí ìtàgé kọ́ ni pé Baba Ijesha ń tẹ ọmọ lára, ẹ yé gbè sẹ́yìn mi lọ́nà àìtọ́ - Yomi Fabiyi