Yorùbá films: Iya Rainbow di ònílé tuntun, ilé méjì ni wọ́n fi ta á lọ́rẹ

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Agba osere Yoruba, Idowu Phillips, ti ọpọ eeyan mọ si Iya Rainbow tun ti di onile tuntun.Ọsẹ to kọja ni osere naa kede loju opo Instagram rẹ pe ileesẹ kan lo fi ile fulaati meji ta oun lọ rẹ ni agbegbe Mowe, nipinlẹ Ogun.Koda, o ni wọn tun fi orukọ oun sọ opopona kan ninu esiteeti aladani naa.