You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Lawal Ayankemi Oluwatoyin: Mo kọ̀ láti máa tọrọ owó nítorí ojú mi tó fọ́, iṣẹ́ ló wù mí
Lawal Ayankemi: Mo ti sọ ireti nu lori aye mi ṣugbọn...Arabinrin yii ṣalaye fun BBC pe gbogbo nkan ṣa deede funfun ni eyi to n ba oun ninujẹ.
Lawal Ayankemi Oluwatoyin to ni ipenija oju ṣugbọn ti ko jẹ ko di oun lọwọ iṣẹ ṣiṣe ṣalaye fun BBC Yoruba ohun ti oju rẹ ri to.
O ni oun ti sọ ireti nu lori bi igbesi aye oun ṣe n lọ lẹyin ti oju mejeeji fọ nigba to fẹ ṣe idanwo JSS3 ipele giram kekere.
- Buhari buwọ́lu bílíọ̀nù N6.45b láti dá ibùdó afẹ́fẹ́ gáàsì sílẹ̀ fún ìtójú àwọn alárùn covid-19
- Ọkùnrin kan dèrò ilé ẹjọ́ lẹ́yìn tó jí aago ọwọ́ tí iye rẹ̀ tó ₦33.8 mílíọ̀nù
- Ọmọ ogún odún jí bàbá ara rẹ̀ gbé, ó gba ₦2m owó ìtúsílẹ̀
- Okuǹrin oníyàwó mẹ́ta fún ọmọ ọdún méjìlá lóyún, ó ní ₦200 ni òun fi tàn án jẹ
- Gbèǹdéke ku àsìkò díẹ̀, Seriki Fulani fohùn ránṣẹ́ sí Sunday Igboho
Ayankemi mẹnuba igbiyanju obi, ati ẹbi rẹ nile iwosan, lọdọ alaafaa ati Wolii ṣugbọn to ja si pabo.
Wọ́n kò bí mi láfọ́jú ṣugbọn ọrọ ti yipada.
Bayii Ayankemi n fi ilẹkẹ dara loriṣiiriṣii bii ko ṣe baagi ati awọn nkan miran fun tita.
- Báwo ní ìpàrójẹ àti ìsúnkì ṣe ń wáyé nínú èdè Yorùbá?
- Àwọn Ọba ló rànṣẹ́ pè mi pé ìyá ìjínigbé àti ìpànìyàn yì tó gẹ́- Sunday Igboho
- Lere Paimo ṣàlàyé bí fíìmù "Ogbori Elémosho" ṣe sọ ọ̀ di Olóyè MFR pẹ̀lú Dangote àti Adenuga
- "Adájọ́, ẹ má tú wa ká, mo sì nífẹ̀ẹ́ ọkọ mi bó tilẹ̀ jẹ́ pé alágbèrè pásítọ̀ ni"
O n ṣe ọṣẹ ifọbọ olomi, egbogi apakokoro atawọn nkan miran.
O ni oun ko fẹ tọrọ owo bikoṣe pe ki oun ri iṣẹ nitori oun kawe de ipele NCE fun ti olukọ tabi ki awọn eeyan maa ba oun ra ọja ti oun n ta.
Mo kọ̀ lati tọrọ owo, iṣẹ ni mo n wa- Ayankemi Lawal.
- ''Ìjọba ìpínlẹ̀ Ondo kò bẹ̀rù idúnkokò mọ́ni iléeṣẹ́ ààrẹ lórí ọ̀rọ̀ àwọn Fulani darandaran''
- Ẹ̀yin èèyàn ìpínlẹ̀ Oyo, mìmì kan kò lè mì yín lónìí- Makinde
- Taa ni ọkùnrin 'tó tan mọ́ Naijiria' tó fún ọmọ Trump, Tiffany ní òrùka ìlérí ìgbéyàwó?
- Ààrẹ Joe Biden tí gba àwọn ọmọ Naijiria láàyé látí wá sàtìpó ní Amẹrika
- Alààfíà ló kú tí àwa Fulani ń wá ní Oyo báyìí- Miyetti Allah