Africa Eye: Wo ìtàn ìyá kan àtàwọn olè ajọ́mọgbé tó n ta ọmọ ní Kenya

Opọ lo ro pe ko si ọna abayọ kuro ninu iya ju tita ọmọ wọn lọ

Orilẹ-ede Kenya ni BBC ti lọ ṣe iwadii àwọn tó ń jí ọmọ gbé ta fawọn to n woju Oluwa ninu iwadii BBC Africa Eye ti ọtẹ yii.

Wo itan iya kan ati awọn ole ti wọn n ji ọmọ gbe ta.

Wọn n ṣafihan awọn ikọ naa ati ọna ti wọn n gba ṣe iṣẹ ibi ọwọ wọn.

Simon Chelugui to jẹ akọwe igbimọ iṣẹ ati idaabobo awujọ ṣeleri pe ọwọ ofin yoo kọ gbogbo wọn

Sarah sọ idi to fi gbiyanju lati ta ọmọ rẹ.

Sarah jẹ ọmọ orukan to jẹ ẹni ọdun mẹtadinlogun nigba to gboyun.