2020 Shiites Ashura day: Àwòráń ọdún Ashura àwọn ẹlẹ́sìn Shiite tí ọ̀pọ̀ ń sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ lórí ayélujára

Kaakiri agbaye ni awọn ẹlẹsin Shiite ti sami ayẹyẹ ọdun Ashura tí wọ́n fi sami ikú Hussein to jẹ́ ọmọ ọmọ Anabi Muhammed (SAW).

Shiite

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Arakunrin ẹlẹsin Shiite kan ree ni ẹkun Kashmir lalẹ ayajọ Ashura ku ọla ni Budgam ni Iwọ oorun Srinagar
Shiite

Oríṣun àwòrán, @IHRC

Àkọlé àwòrán, Awọn ijọ El Zakzakky ni Abuja naa sami ayẹyẹ yii lati ranti iku Hussein to jẹ ọmọ ọmọ Anabi Muhammed
Shiite

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Bayii ni awọn ẹlẹsin Shiite ni Quelta ni Pakistan ṣe sami ayẹyẹ ti wọn pẹlu ẹjẹ ati apa pupọ lati fi ara wọn kẹdun iku Anabi naa
Shiite

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn Shiite ni Iraq pẹlu ogun awọn Karbala lọjọ Ashura ni ẹkun Suq al-Shuyoukh Dhi Qar
Shiite

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn obinrin Shiite ni Karbala n tan abẹla lasiko Ashura fun ibanikédun iku Hussein ni Iraq
Shiite

Oríṣun àwòrán, IMN

Àkọlé àwòrán, Awọn obinrin ẹlẹsin Shiite labẹ Sheikh Ibrahim Zakzaky ni Naijiria n to rin lopopona lọwọọwọ lasiko ọdun Ashura
Shiite

Oríṣun àwòrán, IMN

Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan El Zakzaky ni Shiite n fi ẹjẹ silẹ ni ile iwosan Murital Muhammed ni ipinlẹ Kano lati sami ayẹyẹ ọjọ Ashura
Shiite

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ogunlọgọ ero ni Kashmir ti wọn n sami iku anabi naa pẹlu ọkan ati ara wọn
Shiite

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan Iran kan ree ti wọn ba ina ṣere pọ ati Iraqi ti wọn n sami ayẹyẹ ayajọ Ashura.