Ọba Mohammed bin-Salman ti Saudi yọ ọmọ rẹ̀, Fahad, Abdulaaziz àti àbúrò rẹ̀, Ahmed kúrò nípò nítorí ìwà àjẹbánu

Ọba Saudi Arabiajawe lọ rọọkun nile fun minisita to n ri si eto aabo orile-ede naa.

Ọpọ awọn adari orílẹ̀ ede ati awọn ọmọ oye meji ni Saudi ni wọn ti kọwe gbele ẹ fun ni Saudi.

Ninu iwe ofin Saudi ni Ọba Saudi, Alasẹ Salman ti ni ki ọmọ ọba Fahad bin Turki to jẹ olori ẹṣọ alaabo to tun dari awọn ogun lọ si Yemen pe ko kuro lẹnu iṣẹ rẹ bayii.

Oda, ko yọ ọmọ rẹ silẹ.

Ọmọ rẹ, Abdulaziz bin Fahad, naa jẹ ọkan lara awọn to yọ kuro nipo gẹgẹ bi igbakeji Gomina.

Awọn ọkunrin naa ati awọn mẹrin miran ni wọn n koju iwadii to niṣe pẹlu owo laarin wọn ati ile iṣẹ eto aabo ilu naa.

Ọmọ ọba Mohammed bin Salman, to jẹ ọmọ rẹ ni awọn eniyan maa n fi sọrọ nipa ọba Saudi nitori oun lo n se agbatẹru igbogun ti iwa ibajẹninu ijoba baba rẹ.

Ẹwẹ, awọn alatako sọ pe bi o ṣe n fi panpẹ ọba mu gbogbo awọn eekan ilu, o n dọgbọn san gbogbo igbo didi ti ko jẹ ko de ori oye lọjọ iwaju ni.

Saaju ninu ọdun yii, ni iwe iroyin Wall Street ni, wọn fi panpẹ ọba mu awọn ọmọ ile ọba mẹta, to fi mọ aburo ọba, ọmọ ọba Ahmed bin Abdulaziz ati ati ọmọ oye nigba kan ri, Mohammed bin Nayef.

Eyi to ga julọ to ṣẹlẹ lọdun 2017, ọpọ awọn ọmọ oye, awọn minisita ati awọn olokoowo lo timole si ile itura Rittz- Calton ni Riyadh.

Ọpọ wọn lo pada gba ominira sugbọn lẹyin ti won gba lati sa marundinlaasorin bilionu poun sapo ijoba Saudi ni.

Ọmọ ọba Mohammed bin Salman gba oniruuru iyin lọwọ ilẹ okere nigba to jẹjẹ atipade oniruuru ti yoo ba eto ọrọ aje ati igbayegbadun ara ilu nigba to gori oye lọdun 2016.

Ẹwẹ, oniruuru esun ni wọn fi kan an to fi mọ iku akọroyin Jamal Khashoggi ni olu ile ișẹ Saudi ni Istanbul lọdun 2018 ati erongba lati pa ọtėlẹmuyẹ Saudi Lan to wa ni Canada.

Bakan naa ni wọn ti naka aleebu si ni ọpọ igba lori idarudapọ to n waye ni Yemen, nibi ti ijọba Saudi ti ran ijọba Yemen lọwọ lati maa tẹ ẹtọ awọn obinrin mọlẹ.

Bo tilẹ jẹ pe Ọba Saudi Arabia n fun awọn obinrin ni awọn ẹtọ kan nigba to de, bi i ki obinrin ni anfani lati maa wa ọkọ.