You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Oluwo: Oluwo sọ̀rọ̀ nípa ẹwà rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ọba alayé tó rẹwà gidigidi
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Lara awọn gbajugbaja Ọba ti ko ṣee fi ọwọ rọ sẹyin ni ilẹ Yoruba ni Oluwo ti ilu Iwo nibi ti Kabiyesi Adewale Akanbi ti n jọba lọwọlọwọ.
Nibayii Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi ti jẹ ko di mimọ pe yatọ si pe oun jẹ pataki Ọba, oun tun ni ẹwa.
- Ọmọ Yorùbá mẹ́wàá tó jẹ́ àmúlùúdùn ní Amẹ́ríkà àti Yúróòpù
- Donald Trump ti gbà pé Coronavirus yóò burú jáì kí ǹkan tó dára fún Amẹ́ríkà
- Ṣé lóòtọ́ ni pé Hushpuppi ti kúrò ní ọgbà ẹ̀wọ̀n l'America? Ẹ wo àbájáde ìwádìí wa
- Ṣé Akpabio ṣetán láti dárúkọ àwọn Aṣòfin tó gba iṣẹ́ àkànṣe lọ́wọ́ NDDC?
- Èèyàn 38,344 ló ti ní COVID-19 ní Nàìjíríà lẹ́yìn tí 543 kún un lọ́jọ̀rú
Ninu ọrọ kan to kọ soju opo Instagram rẹ, Oluwo ti ilu Iwo ni ohun to ba wu ẹlẹnu ni ko fi ẹnu rẹ sọ ati pe o da oun loju bi ada pe Ọkunrin to dara loju, dara lẹwa loun jẹ.
Hmmm mo lero pe ọba to rẹwa ni mi!!! Oun eri ewi oun eri ero Adewale seun epe ko se Oba dara o d'ẹjọ lati ilu Iwo, ilu to rẹwa julọ ni gbogbo agbaye"
- Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano tí wọ́gilé ayẹyẹ lẹ́yìn ìrun ọdún Iléyá!
- Wo bí ètò ìsìnkú Tolulope Arotile ṣe lọ nílùú Abuja
- Bàbá mi Aláàfin, ẹ ṣeun ẹ̀bùn owó tí ẹ fún èmí àti ọkọ mi- Lizzy Anjọrin
- Eyitayọ Jegede (PDP) ló máa gbéná wojú Rotimi Akeredolu (APC) nínú ètò ìdìbò Ondo tó ń bọ̀!
- Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ètò ìdìbò kan wà tí erin àti òkúta Dáyámọ́ǹdì leè yí èsì rẹ̀ padà