Lassa Fever: Ìwádìí ní èèyàn 219 ni ibà Lassa pa lọ́dún tó lọ́, 29 lọ́dún yìí, tètè dènà rẹ̀

Lori eto Laahanmi ti BBC Yoruba, a se atupalẹ ohun ti iba Lassa jẹ, ọsẹ to n se lawujọ wa ati awọn ọna ta fi lee dena rẹ.

Fidio naa Laahanmi naa ree:

Iwadi fi ye wa pe awọn ekute ile lo n fa iba yii, eyi to n sekupa ọpọ eeyan lọwọlọwọ bayii.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ẹ wo fidio yii lati mọ iye eeyan ti arun yii ti pa, awsn ohun to n sokunfa rẹ, ami ta fi mọ pe iba Lassa wa lara eeyan kan ati ọna ta lee gba dena rẹ.