Conjoined Twins: Mo rò pé orí mi ni ayé parí sí ni nígbà tí mo bí wọn

Àkọlé fídíò, Wo àwọn ìbejì tó lẹ́ pọ̀ lẹ́yìn àṣeyọrí ìṣẹ́ abẹ dókìtà 70

Gẹgẹ bi iwadii ti ileeṣẹ BBC ṣe lati mọ ipo ti awọn ibeji ti wọn gan mọ ara wọn lati inu oyun wa, aṣeyọri lo ja mọ o.

Awọn ibeji yii wa lara itan aṣeyọri ninu eto ilera lorilẹede Naijiria.

Iṣẹ rèé lọ́wọ́ dokita aadọrin. Wakati mejila gbako lo gba awọn dokita naa.

"Nígbà tí Goodness nìkan kọ́kọ́ jádé nínú yàrá iṣẹ́ abẹ, ìrètí mi gaa... bi Mercy ko ṣe tii jade wa"

Ẹwẹ, nigba ti gbogbo ẹ di aṣeyọri, baba ati iya ọmọ to fi mọ awọn dokita to ṣe iṣẹ abẹ naa atawọn ijọba lo n ṣe ajọyọ pe wọn ri wọn pinya pẹlu aṣeyọri.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: