Xenophobia: Àwọn ọ̀dọ́ kan ń ṣèwọ́de láti pè fún lílé àwọnjì kúrò ní South Africa

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Awọn ọmọ orilẹede South Africa ti da ọrọ ru nibi ti odu oloṣelu kan ti n sọrọ lati dẹkun ikọlu awọn ajoji nibẹ.

Alagba Mangosuthu Buthulez la gbọ pe awọn ọpọ ero kan pa ohun mọ lẹnu nigba ti awọn ọkunrin kan ya wọ agbegbe naa ti wọn si n ke sawọn ajoji lati fi orilẹede wọn silẹ.

Ko din ni eeyan mẹwa, meji ninu eyi to jẹ ajoji ni wọn ti kagbako iku ojiji laarin ọsẹ kan sẹyin.

Ni ọjọbọ lawọn ọlọpaa sọ pe okooleirinwo eeyan lọwọ ti tẹ ati pe awsn ti bomi pa ina ikọlu naa.

Amọṣa ni ọjs aiku lawọn ọkunrin kan tun dide pẹlu apola igi lọwọ ati kums ti wọn si n kaakiri awsn opopona ilu Johanesburg tawọn ti orin 'ajoji gbọdọ fi ilẹ wa silẹ pada si ilẹ wọn" lẹnu wọn, gẹgẹ biiileeṣẹ iroyin abẹle kan, Sowetan Live ṣe kede.

Awọn oluwọde naa kọri si agbegbe Jules Park ni Johannesburg nibi ti alagba Buthelezi, to jẹ ọkan lara awọn aṣiwaju ẹya Zulu lasiko ijsba alawọn funfun nibẹ ti fẹ ba awọn eeyan sọrọ.

Amọṣa n ṣe ni wọn pa ọrọ mọọ lẹnu nibẹ ti awọn fidio tawsn kan ya nibi eto naa ṣe afihan bi awọn eeyan kan ṣe n fi ibudo naa silẹ.