TUNNGR: Ta ló ṣe móríyá fún ọ jù lọ ní Super Eagles?

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles ti Naijiria ti pari ifẹsẹwọnsẹ wọn ninu idije ilẹ Afirka, lẹyin ti wọn pari pẹlu ipo kẹta ninu idije Afcon 2019.

Tunisia ni Super Eagles naijiria fi se ifajẹ ti wọn se ipo keta.

Bi awọn kan se n sọ wi pe Ighalo lo fakọyọ julọ ninu ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles ni idije Afcon naa.

Amọ, awọn miran ni Chukwueze ati Ighalo tiraka ṣugbon Etebo ni fun awọn, ti awọn miiran si ni ẹni miran lo se moriya fun wọn.

Bakan naa ni awọn kan ni gbogbo igba ni ikọ Super Eagles ma n se ipo kẹta, eleyii ti wọn tilẹ pe ni "ogun ibi wa lorilẹede Naijiria".