Awọn ọdọ Ondo fẹ̀họ́nù hàn lórí ìṣekúpani Funke Olakunrin
Awọn ọdọ ipinlẹ Ondo n fẹhọnu han pe ki awon Fulani o kuro lagbeegbe wọn, leyin ti awọn agbebọn pa Funke Olakunri to jẹ ọmọ adari ẹgbẹ Afẹnifẹrẹ lorilẹ-ede Naijiria.
Ọpọlọpọ awọn eniyan lo ni awọn Fulani darandaran lo se isẹ ibi naa ni opopona Ore ni ipinlẹ Ondo.
Amọ awọn ọlọpaa ni awọn ọdọ naa gbe paali pẹlu orisirisi akori, ti wọn si n lọ lọwọọwọ.
- Aago Naijiria ti kún àkúnwọ́sílẹ̀ - Tunde Bakare
- Fulani nìkan kọ́ ló ń pa ènìyàn ní Naijiria -Tinubu
- Àjálù ń bọ̀, tí Buhari kò bá ṣàtúnṣe lórí ètò ààbò- Obasanjo
- Sanwo Olu yan kọ̀míṣọ́nnà 25 àtàwọn olùbádámọ́ràn
- Mahrez dá Super Eagles dùbúlẹ̀ lórí pápá oko tútù
- Ooni Ile ife, Ààrẹ Gani Adams fárígá lórí ikú ọmọ Fasoranti
Awọn ọdọ bẹrẹ ifẹhonuhan pe iku gbigbona ti to gẹẹ nipinlẹ Ondo ati ijinigbe.