Àródan jẹ́ ọ̀rọ̀ Yorùbá tí ìtúmọ̀ rẹ̀ fara sin

Àkọlé fídíò, Wo bí àwọn èèyàn ṣe ń gbẹ́sẹ̀, jupá wa eyín torí itumọ̀ Arodan

Gbajugbaja ni ọrọ yii, "Arodan" paapaa ninu agbo ile nilẹ Yoruba.

Gẹgẹ bi aṣa ati iṣe ati ede Yoruba ṣe ṣe pataki pupọ fọmọ Oodua, ẹ jẹ ki gbogbo wa kọ awọn ọmọ wa nipa wọn fun idagbasoke rẹ̀.

Ẹ gbiyanju tiyin, ti awọn ololufẹ BBC News Yoruba kan ree.

Awọn Iroyin ti ẹ le nifẹ si