Adeboye: Ìkìlọ̀ mẹ́ta tí àgbà ìjọ fi síta nínú ìwàásù f'áwọn Pásítọ̀ ọ̀dọ́

Alufa Agba Adeboye

Oríṣun àwòrán, PASTOR E. A. ADEBOYE/FACEBOOK

Àkọlé àwòrán, Alufa Agba Adeboye
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Oju opo Twitter ti n gbana lati nnkan bi wakati melo kan.

Kii ṣe nitori pe olorin kan tabi elere idaraya kan sọ ọrọ to mu awuyeyewuye wa bi kii ṣe pe ọrọ iwaasu lati ẹnu woli agba kan lo n mu iriwisi orisirisi wa.

Pasito Enoch Adeboye ti ijọ Redeem lorileede Naijiria ki ṣe aimọ foloko. Ti o ba sọrọ, pupọ ninu awọn ọmọ ijọ rẹ lo ma n tẹti lati gbọ.

Ko jẹ iyalẹnu pe o ṣe iwaasu gẹgẹ bi iṣe rẹ amọ awọn amọran kan to gba ninu iwaasu to ṣe nibi eto oloṣooṣu ijọ rẹ ti wọn pe akori rẹ ni Swimming In Glory ti n ja rainrain .

Ki gaan lawọn amọran yii?

Laipẹ yi ni iṣẹlẹ kan to niṣe pẹlu ẹsun pe Pasitọ Biodun Fatoyinbo ti ijọ Coza fipa ba obinrin lo pọ da awuyewuye silẹ.

Pupọ eeyan lo ti n reti ki Pasito Adeboye to jẹ agba ninu ẹsin mẹnu ba ọrọ naa.

Ohun naa sọ ninu fọnran fidio to jade loju opo Twitter pe oun ko fẹ da si ọrọ yii nitori pe abẹ aṣẹ awọn adari ẹgbẹ ijọ onigbagbọ ni oun wa. Amọ nigba ti yoo fi gba awọn eeyan ni amọran ọrọ naa dabi ẹni pe o nṣe afiwe ọrọ to n lọ lode nipa ifipabanilopọ ni.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Ninu fidio naa o gba awọn pasitọ ọdọ ni imọran nipa nnkan mẹta to ni o wa ninu Bibeli

  • O ni ko si nnkan to pamọ ti ko ni lu sita. O le pẹ titi ṣugbọn lọjọ kan asiri yoo pada tu
  • Yago fun ifẹkufẹ oju gẹgẹ bi ọdọ. Ma sọ pe ẹni ami ororo ni ọ, beere lọwọ Samsoni ninu Bibeli...
  • Ni temi, mi o ni ni akọwe obinrin kankan ritori pe ti obinrin ba fi ẹsun kan ẹ, ko si ẹni ti yoo gba ọ gbọ koda ki o jare.

Ki lawọn eeyan sọ loju opo Twitter

Iriwisi ṣe ọtọọtọ lori ọrọ rẹ ti a mọ pupọ lo kan sara si i pe o ṣe iwaasu to m'ọgbọn wa.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Amọ awọn miran tako ọrọ rẹ to sọ nipa yiyan akowe obinrin

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Awọn ẹlomiran tilẹ mu amọran tiwọn to yatọ si ti Pasito Adeboye wa lọna ati dẹkun ifẹkufẹ oju

Skip X post, 5
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 5