Kí ni àmì ohùn 'Aguntaṣọọlo'?
Gbajugbaja ni ọrọ yii, "Aguntaṣọọlo" paapaa laarin awọn alagbe, olorin atawọn iyaagba ti wọn fẹ ki awọn ọmọ wọn.
Awọn olorin a ni, 'aguntaṣọọlo, ọkunrin ogun' ati bẹẹbẹẹ lọ; ṣugbọn ki ni ami ohun ti ede Yoruba fi si ori ọrọ yii?
Ẹ gbiyanju tiyin, ti awọn ololufẹ BBC News Yoruba kan ree
- Ọmọkùnrin tó pa ọmọ igbákejì Gómìnà Ondo gba ìdàjọ́ ikú
- '$800 ni Amẹ́ríkà ń fún ọmọ Yorùbá tó bá gba ìṣẹ́ ológun rẹ̀ lóṣooṣù'
- Ẹ wo ọmọ ọdún méjì tó mọ orúkọ orílẹ̀èdè 40, àwọn ààrẹ l'ágbàáyé láì lọ síléèwé
- Ìpanu ‘Cheese ball’ ni wọ́n fi jí Ikimot gbé, àmọ́ ó padà sílé lẹ́yìn ọdún márùn-ún
- ìfipábánilòpọ̀: Má dákẹ́ - Oluwaseun
- Wọ́n ta ère Ọ̀ṣun Osogbo sí Togo - Bàbá Ọṣun figbe ta
- World TB Day: "Ó dùn mí jù pé ń kò rí ọmọ mi fún ọdún kan"
- World water day: Ẹrin Ijesa, Ọ̀ṣun Oṣogbo, àwọn ibùdó ìgbafẹ́ omi tí ó yẹ kí o mọ̀