Lagos building collapse: Àwọn òbí ń kérora lórí ikú àwọn ọmọ wọn nínú ìjàmbá ilé tó wó
Awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi ti lee kuro ni ibudo ijamba ile to wo ni Itafaji niluu Eko, ṣugbọn irora ina sms to jo awọn obi kan ati ọmọ wọn ti o n gba iwosan pẹlu oniruuru ifarapa ko lee kuro lọkan awọn obi, alagbatọ ati ẹbi awọn to farakaaṣa ijamba naa ko lee tete kuro bẹẹ.
Pupọ lo padanu ọmọ kan meji tabi ju bẹẹlọ ninu iṣẹlẹ yii.