BBC Yorùbá: Àwọn akọ̀ròyìn wa ti lọ káàkiri láti jábọ̀ ìròyìn ìbò
Ni ọjọ Satide, ti eto idibo gomina yoo waye, ileesẹ BBC Yoruba ti fọn awọn akọroyin rẹ sigboro lati maa tọpinpin awọn isẹlẹ to n lọ lawọn ipinlẹ gbogbo lorilẹede Yoruba.
Nitori naa, a n rọ̀ yin lati darapọ mọ awọn oju opo ikansira ẹni ti BBC Yoruba, fun awọn iroyin to n lọ nipa eto idibo yika orilẹede yii.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Seyi Makinde làwa ń bá lọ lọ́jọ́ Satide - Ladọja
- Bí mo ṣe ń tako Buhari bá ìjọba tiwantiwa mu - Ọbasanjọ
- Ìbò sáà kẹta fún Ajimọbi ni ìbò Adelabu, ẹ yàgò fun - Seyi Makinde
- Níbo lowó ìrànwọ́ ẹ̀kọ́ wa wà - Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Kwara ń bèèrè?
- Ọbasanjọ ni ọmọ òrùkàn tó di olóri orílẹ̀èdè lẹ́ẹ̀mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀
- Kìnìún tí wọn ń sìn yarí, ó pa olówó ati ọmọ olówó rẹ̀
- Èmi àti Ọbasanjọ leè yapa nínú òṣèlú, àmọ́ mo ń bọ̀wọ̀ gidi fun - Buhari
A tun n rọ yin lati maa fi awọn ohun to ba n lọ ni ayika wa ransẹ si wa, boya aworan ni, fidio abi iroyin.