You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Elections Update 2019: Ẹ fún wa ní ìbò wa lẹgbẹ́ PDP ń kigbe
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú People Democratic Party (PDP) tí bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónú han pẹ̀lú ìwọ́de lọ si olú ilé iṣẹ́ àjọ elétò ìdìbò INEC, lórí èsì ìdìbò tó wáyé ní ọjọ́ Kẹtàlélógun oṣù Kéji ọdún 2019.
Àwọn tó péjú níbi ìwóde náà ni alága ẹgbẹ́ òṣèlú PDP, Uche Secondus, àgbẹnusọ ẹgbẹ́ PDP, Kola Ọlọgbọndiyan, pélù àwọn ọmọ ẹgbẹ́ míràn bii ẹgbẹ́run ti wọn si ń kígbe "Atikulated"
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Tí ẹ ò bá gbàgbé, ẹgbẹ́ òsèlú PDP tí Alhaji Atiku Abubakar soju fun bii oludíje sipo ààrẹ, kọ èsì ìdìbò ààrẹ tó wáyé nínú oṣù tó kọja