Election Update 2019: Àwọn aráàlú ń fapá jánú lórí ìdádúró tó bá kíka èsì ìbò ààrẹ

Mahmood Yakubu
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Ọpọ awọn ọmọ orilẹede Naijiria lo ti n fapa janu lori bi alaga ajọ eleto idibo, Mahmood Yakubu se n kede idanuduro lọpọ igba lasiko ti wọn n ka esi ibo aarẹ nilu Abuja.

Esi ibo aarẹ naa ti wọn bẹrẹ kika rẹ ni aago mejila ọsan titi di aago kan oru, ni wọn siwọ kika rẹ, ti wọn si n lọ fun isinmi ranpẹ ni igba mẹrin ọtọọtọ.

Awọn idanuduro to n waye yii lo bọ si apo ibinu awọn ọmọ Naijiria ti oju wọn wa lọna lati mọ ẹni ti yoo jawe olubori gẹgẹ bii aarẹ tuntun fun orilẹede yii.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Loju awọn opo ikansiraẹni bii Twitter, Facebook ati Instagram, ẹnu awọn ọmọ naijiria ko duro, ti wọn si n kun lori bi ajọ eleto idibo se n danu duro lọpọ igba

Lero tọpọ eeyan, wọn ni ibo taa ti di lati ọjọ Satide se wa n sun wọ ọjọ isẹgun ki wọn to kede ẹni to jawe olubori.

Esi ibo aarẹ

@meizam0 loju opo Twitter, o ni, isinmi ranpẹ melo gan ni ajọ Inec fẹ gba gan?

Wicked Majidi @BodaMagidi ni idaduro ranpẹ miran? Se o ti yararẹ ọga Yakubu lẹẹkan si ni?

Ta ba tete se nkan si, ajọ eleto idibo yoo lo ida ọgọta ninu ọdun mẹrin to yẹ ki ẹni to jawe olubori lo lati fi kede esi ibo. O ya, se a lee dawo jọ fun ọga agba ajọ INEC lati ra Lucozade fun?

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

@nnekish ni Alaga ajọ INEC yii gan sa. Isẹ gan soso lo ni, isẹ kan pere, o si n lọ fun isinmi ranpẹ ni gbogbo igba, o da mi loju pe o ni ju iyawo kansoso lọ.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

@Buzzifyer, o sọ pe eeyan kan nilo lati se bii Orubebe fun alaga ajọ INEC yii, ki lo nilo isinmi wakati mẹsan fun? Pẹlu bo se n lọ yii, yoo gbato ọsẹ kan ko to le kede ẹni to wọle sipo aarẹ.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

@alayeburna n tiẹ ni Se bi alaga INEC ni oun ni awọn ojulowo esi ibo ni ori ẹrọ ayarabiasa rẹ ni?

Se ko da loju mọ ni? Asiko yii gan lo yẹ ka maa fi ojulowo esi ibo ko ajọ INEC loju.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

@iam_stephenakin n beere pe Ki ni gbogbo eleyi gan?

Skip X post, 5
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 5

Sallie_junaid, o ni Se aisan n se alaga ajọ INEC ni? Ki lo de to n lọ fun isinmi ni gbogbo igba?

Skip X post, 6
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 6

@governordhaniel, o ni a jọ ku sibi ni. Se INEC ro pe a lọ sun, ko wa lọ paarọ esi ibo. Ọga Mahmood, lọ fun isinmi rẹ, awa yoo la oju wa silẹ laisun.

Skip X post, 7
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 7