2019: Wo fídíò bí wọ́n ṣe sọ nǹkan lu àwọn adarí APC l'Abẹokuta

Àkọlé fídíò, 2019: Wo fídíò bí wọ́n ṣe sọ nǹkan lu àwọn adarí APC l'Abẹokuta

Iroyin sọ pe awọn janduku naa bẹrẹ si nii lọ kaakiri ijoko ni papa iṣire naa ti wọn si n le awọn ti wọn ba funra si pe wọn jẹ ololufẹ Dapọ Abiọdun kuro ni aye wọn.