Jimi Agbaje: Kò sí òfin tó ni a gbọ́dọ̀ gbàyè láti lẹ ìwé ìpolongo
LASAA ni Jimi Agbaje ko gba aṣẹ ki o to lẹ awọn iwe ipolongo rẹ lori Third Mainland Bridge ni, ṣugbọn oludije naa ni LASAA kan n fi ọrọ bo oun to ṣẹlẹ gangan mọlẹ ni.