You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
HIV AIDS: Ìdí tí o kò fi lè kó àa[rùn HIV nínú itọ́
Koko HIV wa lara awọn arun to jẹ ipenija nla lagbaye ninu eto ilera lẹyin ti o ti gbẹmi eeyan bii marundinlogoji.
Ajọ to to n ri si eto ilera lagbaye(WHO) ṣalaye pe eeyan miliọnu kan to ni aarun HIV lo padanu ẹmi wọn lọdun to lọ lasan.
Iwadi fihan pe eeyan miliọnu mẹtadinlogoji lo larun HIV lagbaye ti ida aadọrin ninu ọgọrun si wa lati ilẹ Afirika- bẹẹ eeyan to din diẹ ni miliọnu meji ṣẹṣẹ lugbadi aarun ọhun ni ọdun 2017 nikan.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Ẹni to ba ni kokoro HIV nikan lo le ni aarun AIDS.
Ọpọ nnkan lawọn eeyan ti n sọ nipa aarun AIDS lati igba ti o ti kọkọ jade ni bi ogoji ọdun o din dẹ ṣẹyin.
Ṣugbọn ko si otitọ ninu ọpọlọpọ ọrọ naa.
Irọ: Mi o le ni kokoro HIV ti mo ba n bawọn to ni kokoro HIV gbe
Ero yii ti ṣe okunfa ki ọpọ eeyan maa ba awọn ti wọn ni kokoro HIV ṣe papọ fun ọjọ pipẹ.
Lẹyin inalilọyẹ ati ipolongo lori aarun HIV AIDS, ida ogun ninu ida ọgọrun awọn eeyan Ilẹ Gẹẹsi si gbagbọ pe eeyan le lugbadi aarun naa nipa fifi ara kan ara tabi ninu itọ.
Ṣugbọn eeyan ko le karun HIV AIDS nipa fifi ara kan ara, tabi omi oju, oogun, itọ tabi itọ.
O ko le ko aarun HIV AIDS nipa:
- Mimi afẹfẹ sinu
- Didi mọ ara ẹni, fifẹnu ko ara ẹni lẹnu, tabi nipa biba ọwọ
- Fifi abọ kan naa jẹun
- Pipọn omi nibi kan naa
- Lilo nkan pọ
- Lilo ohun elo kan naa papọ
- Fifi ọwọ kan ijoko ile iyagbẹ tabi ọwọ ilẹkun
Kokoro HIV maa n ran nigba ti omi ara ẹnikan ba dapọ mọ ti tẹni to ba ni aarun naa, fun apẹrẹ, ẹjẹ, atọ, omi oju ara obinrin ati omi ọyan.
Irọ: Oogun ibilẹ le wo aarun HIV san
Irọ funfun balau ni. Oogun ibilẹ, iwẹ lẹyin ibalopọ tabi ibalopọ misconception ko le wo aarun HIV AIDS.
Wiwẹ pẹlu ọmọbinrin tii ko mọ ọkunrin to le wo aarun HIV AIDS san.
Irọ nla ni pe o le tara ẹfọn ni aarun HIV
Irọ ni pe o le ko aarun HIV lati ibasun ẹnu.
Wiwọ rọba idaabobo(condom) ko sọ pe ki eeyan maa lugbadi aarun HIV.
Irọ nla ni pe awọn to ba larun HIV maa n ku ni kekere
Alaboyun to ba ni aarun HIV, ọmọ rẹ le maa ni aarun ọhun