Bidemi Ajulo: Gèlè tí ẹ kọ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára kò dájú

Àkọlé fídíò, Ẹ wo àrà tí ẹ le fi gèlè dá láàrín ìṣẹ́jú mẹ́ta

Aṣaralóge ni Omidan Bidemi Ajulo, ó jẹ́ kó di mímọ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹni tó kọ́ iṣẹ́ gèlè wíwé pé àyàfi tẹ́k bá kọ́ ọ lójúkorojú, fífi ẹ̀rọ ayélujára kọ́ gèlè kò dájú.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: