Mimiko: Ọlọ́run ń sọ ǹkan fún mi...
Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, Olusegun Mimiko tó jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo tẹ́lẹ̀ rí ti ṣí kúrò láti ẹgbk òṣèlú kan sí òmíràn.
Láìpẹ́ yìí ló kúrò láti ẹgbẹ́ òṣèlú PDP lọ sí ẹgbẹ́ Labour Party níbi tí ó ti kédé èròngbà rẹ̀ láti du ipò ààrẹ ní ọdún 2019.