'Ìbí kò ju ìbí, Èèyàn bíi tiyín ni àfín, ẹ dẹ́kun dídẹ́yẹsí àfín'

Àkọlé fídíò, Bimpe: Èèyàn bíi tiyín ni àfín, ẹ dẹ́kun dídẹ́yẹsí àfín

Bí Ọlọrun ṣe dá ààwọ̀ ara wa nìyí, àfín kò yàtọ̀!

Adeọṣun Fọlaṣade ba BBC Yorùbá sọrọ lórí ìhùwàsí awọn eniyan ti wọn ba ti ri afin ati bi eyi ṣe le ṣakoba fun iru afin bẹẹ ni awujọ.

O gba awọn eniyan nimọran pe 'E ma fi ọ̀bọ lọ àfín mọ́ nitori pe ìbí kò ju ìbí'.