Ìgbésí ayé àwọn ọmọdébìnrin wọ̀nyìí di ọ̀tun láti 2008
Oriṣii idanilẹkọọ ló n fun awọn èwe yii lasiko eré bọọlu
Fatimah Abdulkadir Adan n fi ẹkọ nipa ere bọọlu gbigba tun igbesi aye awọn ọmọbinrin agbegbe rẹ ṣe.
BBC Innovations pẹ̀lu ajọṣepọ ilé iṣẹ arannilọwọ ti kii ṣe tijọba, iyẹn, Bill and Melinda Gates Foundation.