Small Doctor, Temi Adekunle: Inú ilé ilẹ̀ ni wọ́n sọ àwo orin àkọ́kọ́ tí mó gbé jáde sí ní 2001

Àkọlé fídíò, 'Ìyá Tíṣà lòdì sí kí n mutí, fagbó tàbí sìgá'

Mi ò fi igbò tàbí sìgá kọrin rí

Ní ìgbà tí ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ, Small Doctor jk kó di mímọ̀ pé kò dẹrùn.

Omo Iya Tisa sọrọ nipa ibẹrẹ iṣẹ orin rẹ ki eledaa to wa gba fun un.

O ṣalaye pe ipele SS1 iwe kinni ile ẹkọ girama onipele keji ni oun wa nigba naa.

Temi Adekunle gba awọn ọdọ niaynju lati ṣọra fun iwa aidara.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: