Irinṣẹ́ òǹkà ọdún ti wà láti ka iye ọdún tó leè lò láyé

Njẹ́ o mọ̀ pé, iye ọdún tó ṣeé ṣe kí gbogbo ènìyàn lò láyé, ti fi ọdún méje pọ̀ si láti ọdún 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà ọdún yìí, yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀, ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè to ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Móríwú

  • Aworan obinrin nọọsi kan to joko, ti o si fi ọwọ mejeeji n tẹ ẹrọ igbalode
  • Aworan aja naa wa lapa ọtun ti awọn eeyan kan to mu foonu dani to n wo aworan awọn to gbe aja dani wa lapa osi
  • Aworan ori pẹpẹ ijọ tawọn agbebọn naa kọlu ni apa osi, aworan agbebọn kan pẹlu ibọn atamatase ati okun ọta ibọn lọwọ rẹ
  • Aworan irun ti wọn n fi ọsẹ amurungun si i ati eroja ti won n lo fun un.
  • Ere ti wọn gbẹ ni obinrin, o wọ aṣọ funfun, ilẹkẹ wa ni ọrun rẹ
  • Awọn obinrin ro iro funfun mọ aya wọn, wọn joko silẹ lasiko ọdun Ẹlẹgba Ejiwa
  • Aworan awon to n se ifehonuhan ni orileede South Africa
  • Aworan akara oyinbo ti wọn fi mọ sọọsdi katidir, o ni awọ buluu, eeru ati pinki
  • Alaye lori ohun to sele ni Mali
  • Aworan Lisabi Agbongbo Akala, akọni ilẹ Egba
  • Alaye nipa atọ ọkunrin
  • Suliat Epo Akara
  • Aworan Aworo oriṣa Awodi

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ

  1. 8
    Àjọ INEC kéde Muhammadu Buhari bíi ààrẹ fún sáà kejì