Nigeria Presidential elections 2023: Wo èsì ìbò ààrẹ fún Tinubu, Atiku, Kwankwaso, Obi

Lọ́dún 1999 ni Naijiria ti bẹrẹ eto iṣejọba alagbada pẹlu ẹgbẹ oṣelu PDP àti ẹgbẹ APC.

Awọn ẹgbẹ mejeeji yii lo ti n ṣakoso Naijiria lati 1999 titi di isinyi ṣugbọn lọtẹ yii awọn ẹgbe\oselu Labour Party naa ti n ba wọn figa gbaga pẹlu NNPP.

Peter Obi ni oludije lati inu ẹgbẹ Labour Party nigba ti Rabiu Kwakwanso jẹ oludije lẹgbẹ NNPP lasiko yii.

Awọn ọdọ Naijriia sọ pe awon ti ṣetan lati dibo lasiko yii pẹlu ariow lori ayelujara.

Ida kan ninu mẹta ninu eeyan to dagba to lati dibo ninu eeyan milionu mtadinlaadọrun to yẹ ko didbo lasiko yii.

Aago mẹjọ aabọ ni eto idibo ti bẹrẹ nibit i awọn eeyan mi ti n sọ pe awọn ko tii ri ibo di ni agbegbe wọn.

BVAS to jẹ Bimodal Voter Accreditation System ni wọn n lo ninu eto idibo ti ọtẹ yii.

Ika owo ati dida oju oludibo mọ ni wọn n lo.

Oludije to ba wọle nilo ibo ida mẹẹdọgbọn ninu ọgọrunun ni o nilo ninu ida meji ninumẹta awọn oludibo ni ipìnlẹ mẹrindinlogoji tó wa ni Naijiria pẹlu Abuja.

Wo bi Esi Idibo naa ṣe n jade nibi yii:,..........