2023 Nigeria Election: Ìgbàgbọ́ wa ní pé Nàìjíríà ṣì máa dùn lẹ́yìn ìdìbò ọ̀la yìí- Àwon olùgbé Nàìjíríà

Idibo yii naa lo le fun wa ni ayipada ti a n fẹ ni Naijiria, a maa dibo bo tilẹ jẹ pe ẹbi n pa wa.

Tẹlẹtẹlẹ nkan ko ri bayii rara ṣugbọn o ti wa le ju agbara wa lọ bayii

A ko ri owo na, ebi n pa wa ṣugbọn sibẹ-sibẹ a ṣetan lati dibo fun e\ni to maa mu igab ọtun de ba Naijiria.

BBC Yorùbá jáde lọ bèèrè bóyá àwọn eèyàn máa gba owó lọ́wa ẹni tó ba fẹ́ ra ìbò wọn?

Opọlọpọ lo sọ pe awọn ko ni ta ibo awọn rara nitori pé awòn ko ni fẹ ki iay tun jẹ awọn.

Awọn mii sọ pe koda ki awọn agba owo lọwọ awọn oloṣelu, ẹni to wu awọn lawọn ṣi maa dibo fun lasiko idibo.

Opọ \moọ Naijiria lo gabdura fun alaafia ati isinmi léyin idibo ọla yii pe didun ni ọsan a so laṣẹ Olodumare.