You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Day 22: 'Obìnrin ló ni ilé àti àdúgbò fún ìdí èyí wọ́n lè ṣe ìlú dáadáa'
Iṣẹ́ ìlú yàtọ̀ gidigid si iṣẹ́ ilé ni igbagbọ ẹlomii.
BBC Yorùbá jade kaakiri lọ wadii boya awọn obinrin funra wọn ti ṣetan lati gbe obinrin ẹgbẹ wọn sori aleefa iṣejọba alagbada.
Eyi wu mi ti ko wu ọ lo jẹ ki èrò wọn kó dọgba si idahun ibeere naa.
- Bí ìgbáradì fún ètò ìdìbò ṣe ń lọ káàkiri ilẹ̀ Yorùbá nìyí
- Gbajúmọ̀ Òṣèré apanilẹ́rin Sisi Quadri pàdánù ìyà rẹ̀, omijé bọ́
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- Àlàyé rèé lórí ìdí tí EFCC kò fi tíì mú ẹnikẹ́ni fún kíkó Naira tuntun pamọ́
- 'Àwọn ọkùnrin gan mọ̀ pé àwọn nílò àwa obìnrin nínú òṣèlú, ìdí tí èmi fi wọ òṣèlú ni pé...'
Awọn kan gba pe ko le rọrun rara lati fiṣẹ ilé bii ina dida kuniṣẹ ìlú ati pe Olorun ti gbe iṣẹ adari fawọn ọkunrin lati ibẹrẹ.
Ohun to kọiwaju sẹni kan, ẹyin lo kọ si ẹlomii bi ilu gangan, awọn mii ni obinrin lo ni ile, obinrin naa lo ni ìlú ni eyi to fihan pé ko si nkan ti ọkunrin n ṣe tobinrin ko le ṣe.
- Olùdíje sílé ìgbìmọ̀ aṣòfin pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ sọ́wọ́ àwọn agbébọn ní ìbò ku ọjọ́ kan, wọ́n tún dáná sun òkú rẹ̀
- Tani Auxilliary tí Teslim pé ní 'Ex convict' tó ń bí Makinde nínú-
- Mọ̀ síi nípa ewu tó rọ̀ mọ́ níní ìbálòpọ̀ lásìkò ìlóyún lórí ètò Sé lóòtọ́ ní BBC
- Ọmọ tí wọ́n bá fi èdè Yorùbá kọ́ ní ẹ̀kọ́ máa ń pegedé jú tí èdè míràn lọ- Ọjọgbọn Ogundeji
- Wọn kò tíi bí ọkùnrin tí kìí ṣe ṣìná sáyé- Olori Sekinat Elegushi
Wọn fẹnuko pe ti ọpọlọ obinrin naa ba pe, ko si ohun to buru ninu gbigbe agabra adari le won lọwọ paapaa lasiko yii to dabi pé awọn ọkunrin ti kuna ninu iṣẹ ìlú ni Naijiria loju ti wọn.