You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ekiti 2022: Wo ǹkan méje tí ó kò mọ́ nípa Oyebanji (APC); Kolawole (PDP), Oni (SDP) àti Ajayi (YPP)
Wo ǹkan méje tí ó kò mọ́ nípa Oyebanji (APC); Kolawole (PDP), Oni (SDP) àti Ajayi (YPP)
Eto Ididbo Ekiti gbera sọ lọjọ Abamẹta, ọjọ kejidinlogun, Oṣu kẹfa, ọdun 2022.
Enikẹni to ba bori ninu eto idibo yii ni yoo gbegba oroke. ti yoo si di gomina kẹjọ ti yoo ṣakoso ipinlẹ naa.
Ajọ eleto idibo Naijiria, Independent Electoral Commission, INEC ni yoo ṣeto idibo naa.
Lati igba ti iṣejọba awa ara wa ti bẹrẹ ni Ekiti, ko tii si ẹgbẹ oṣelu kan naa to gbe ijọba kalẹ fun ọmọ ẹgbẹ wọn kan naa ri.
- PDP ṣetán láti kéde olùdíje igbákejì ààrẹ fún Atiku
- Ariwo kò yẹ kóo máa gbé Kùránì dání pẹ̀lú iṣẹ́ aṣẹ́wó tí ò ń se ní wọ́n pa kí wọ́n tó dáná sun òkú náà
- Nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Olaniyi Ben Agboola, olúdíje ẹgbẹ́ PRP nínú ìdìbò gómìnà ipinlẹ Ekiti
- Ajagunigbala Moses Olajide, pásítọ̀ tó fẹ́ di gómìnà ipinlẹ Ekiti lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ AAC
- Ǹjẹ́ o mó Oladosu, ọmọ Peter Fatomilola tó jẹ́ olùdíje ẹgbẹ́ òṣèlú NNPP-
- Adájọ́ da ẹjọ́ Ilana Omo Oodua nu, tó ní kí wọn wọ́gilé ìbò gómìnà Ekiti àti Osun