You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Jesse King Buga: Alùfáà CAC ni Bàbá mi, Ìyá tó ń dúró ti ọmọ nígbà ìṣòro ní ìyá mi
O ṣeẹṣe láti ní ìyàwó kan pẹ̀lú àìbalẹ̀ ọkàn tàbí àádọ́ta pẹ̀lú ìbàlẹ̀ ókàn, oore ọ́fẹ́ ló bá dé- Jesse Buga King
Jesse King Buga ni gbajugbaja onkọrin to ki iya rẹ ti gbogb aye si tẹwọ gba a.
BBC Yoruba ni Buga gbalejo lasiko to n sọ nipa iriri aye re, ohun ti oju rẹ ti la kọja ati bẹẹ bẹẹ lọ.
O ṣalaye bi oun ṣe jẹ ọmọ ipinlẹ Edo ti a bi si Ibadan ni ipinlẹ Oyo to si dagba ni ipinlẹ̀ Eko.
- A óò yọ àwọn ọmọ Naijiria kúrò nínú ìṣẹ́, òṣì, ìṣòró ètò aàbò àti àìmọ̀kan- Tinubu
- Ọlọ́pàá Oyo bẹ̀rẹ̀ kán lu ìgbó láti wá àwọn ajínigbé lópópónà Lagos-Ibadan Expressway
- Wo bí àbẹ̀wò ọjọ́ méjì tí Aarẹ Buhari ṣe sí Kaduna yóò ṣe lọ
- Àwọn gbajúmọ̀ ọmọ Yorùbá márùn ún tó gbégbá àpótí òṣèlú ní Nàìjíríà
- Hajiya Binta Balarabe Kubaus rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́wàá he lẹ́yìn tó lu jìbìtì ₦5.5m
Buga sọ ohun to bi orin : Mummy ooo, wa pé laye.... Mummy oooo wa jẹun ọmọ ninu ifọrọwanilẹnuwo naa.
Bakan naa ni o sọ ninu ohun ti oju rẹ ti ri to laye.
- Ìdí tí mi ò fi lègbà kí ẹnikẹ́ni fọwọ́ tẹ ara mi gẹ́gẹ́ bí olórin-Sola Allyson
- Kìí ṣe dandan kó jẹ́ èmi ṣùgbọ́n ẹ dìbò fún eléré láti di ààrẹ tàbí gómìnà
- Lóòtọ́ ni mo yìnbọn níbi yánpọnyánrin tó wáyé ládúgbò mi-Seun Kuti
- Èmi àti Kolington kò fẹ́ra padà o, ọba Wákà kò fẹ́ ọba Fuji mọ́ - Salawa Abeni
- Onínúfùfù ni Saheed Oṣupa, ṣùgbọ́n èèyàn dáradára ni-Taye Currency
- Èmi kìí mu oògùn olóró tàbí ọ̀tí àmọ́ wèrè gidi ń bẹ lára mi – Portable Zazzu
- Màmá mi jẹ́ ọ̀gá akọrin ní ṣọ́ọ̀ṣì C&S ní Ile Ife, níbẹ̀ ni mo ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ- Bisi Alawiye
- Ìjọba Buhari ti gbẹ́rù tó kọjá orí, bàtá tó bá ń ró lákọ fẹ́ ya ni!- Tunde Bakare
Buga gba awọn ọdọ niyanju lati ni aforiti ki wọn si ma sọ aṣa ati ede wa nu.
O tun ni ki awọn agba naa ma fi nkan han ọmọde nitori pe, oriṣa ti a ko ba fi han ọmọ kii pẹ parun.