Taye Osinowo Olaosebikafi Iyabo Ojo, Mide Martins, Jaye Kuti, Afeez Owo àtàwọn míì dárà ap

O kan wu mi lati maa se nkan lona to yatọ ni mo se bẹrẹ iṣẹ yii- Booda Taye Oniyakuya

Ogbeni Osinowo Taiwo Olaosebikan jẹ gbajugbaja ayaworan ẹni lọna to panilẹrin pupọ.

Ori Instagram ni ọpọ ti maa n rẹrin lori aworan Booda Taye Oniyakuya.

Booda Taye Oniyakuya salaye idi ti oun fi n ya aworan awọn eeyan lọna to yatọ.

Bakan naa lo gba awọn ọdọ niyanju lati maa ṣe ohun to wu wọn lọna to yatọ.