You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Babajide Sanwo Olu, El Rufai: Mo ṣetán láti dojú ìjà kọ ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ bá ọ̀rọ̀ ajé Eko jẹ́- Sanwo Olu
Mo ṣetán láti dojú ìjà kọ àwọn tó fẹ ba ọrọ ajé Èkó jẹ
Gomina Babajide Sanwo-Olu ipinlẹ Eko tí seleri lati koju gbogbo awọn to ba n gbero lati tẹ oju ọrọ aje Eko mọlẹ.
O fidi ọrọ yi mu'lẹ lasiko to n gba akẹgbẹ rẹ lati ipinlẹ Kaduna Nasir El-Rufai lalejo ni ile ìjọba.
- A kó ní sanwó oṣú ASUU láìjẹ́ pé wọ́n gba IPPIS- Ìjọba Àpapọ̀
- Ìdájọ́ ikú ló bá dé fáwọn méjì tó fipá bá ọmọ ọdún mẹ́rìnlá lò pọ̀
- Bí àwọn kan tí ń ní àtimọ̀lé tí wọ́n sọ olorin Nazir sí ní Kano ni ọwọ́ kan òṣèlù ní àwọn mii ní...
- Ẹkún àti ìbànújẹ́ láwọn mọ̀lẹ́bí fi sìnkú ọmọ méje ní Kumba, Cameroon lónìí
- Wo bí àwọn ọmọ Nàìjíríà ṣe n kí fún ìjọba nítorí $1.2bn Naira tó fẹ́ ẹ yá lọ́wọ́ Brazil
Sanwo-Olu ni ijọba oun n wa gbogbo ọna ajọṣepọ ti yoo mu ki ipinlẹ Eko gberasọ padà.
Bakan naa lo salaye pe: ijọba ko ni yẹ lati ri pe ayé ko gba gbogbo awọn to ba fẹ ba eto ọrọ aje ipinlẹ naa jẹ.
O ni toun ti gbogbo rogbodiyan to tẹle iwọde ENDSARS oun ṣetan lati fidi idajọ ododo rinlẹ fun awọn to farakasa ijiya eyikeyi lọwọ àwọn ọmọ ikọ SARS
Ninu ọrọ tirẹ Gomina Kaduna Nasir El-Rufai ni omije fẹ lè máa bọ loju oun nigba toun ri akoba t'awọn janduku ṣe ni Èkó.
O ni ara wọn ni awọn to ba nkan ilu jẹ da loro ati pe bopẹ boya wọn yóò jèrè àkóbá ti won ṣe.
"A o ṣe gbogbo nkan ti ipinlẹ Eko ba nilo ká ṣé ni iranwọ lati le gbe Eko dide pada"