Coronavirus Cases in Africa:Ẹ wo ọ̀nà tí àwọn èniyàn ń gbà rí oúnjẹ̀ jẹ lásìkò àrùn Coronavirus
Ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ ènìyàn ló ti fí èrò wọn hàn nípa bí ebi àti ìṣẹ́ ṣe ń bá àwọn ènìyàn fínra nílẹ̀ Afrika lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus.
Amọ àwọn to n ta ounjẹ lori ẹrọ ayelujara fún àwọn eniyan mu irọru ba awọn eniyan.
Ọkan lara awọn to ba BBC Yoruba sọrọ ni iye awọn eniyan ti oun ta ounjẹ fun lati igba ti ajakalẹ arun Coronavirus to bẹ silẹ ni Naijiria ti peleke si ju ti tẹlẹ lọ.
Ẹ wo fidio naa fun ẹkunrẹrẹ ọna ti awọn eniyan n gba lati ri ounjẹ jẹ lasiko ofin konile o gbele lorilẹede Naijiria yii.