#HowGodMademechallenge: Ṣe lóòtọ́ bí àwọn olólùfẹ́ BBC Yoruba ṣe rí rè é?
Orisirisi iroyin ni ileeṣẹ BBC Yoruba ma n gbe jadeki awon araalu le mo bo ṣe n lọ lagbaye.
Amọ ati ri wi pe lọpọ igba awọn eniyan fẹran iroyin ofofo tabi ti awọn oṣere ni ilẹ Yoruba.
Iroyin ni Ede Gẹẹsi ko bawọn lara mu rara, bẹẹ ni wọn fẹran lati ma a bu eebu ni Comment Box.
Oya ẹ wa foju lo n jẹ ninu fidio yiii: