You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ṣìṣe-ṣìṣe bá Man City, Norwich fi wọ́n ṣe fàájì òpin ọ̀sẹ̀
Ile mi jiji ni papa iṣere Carrol road nibi ti Norwhich ti da Man City lagbo sina pẹlu goolu mẹta si meji.
Pupọ awọn to nfi kan ba ere bọọlu bọ ni esi naa j iyalẹnu fun ti onikaluku si n bere pe ki lo ṣẹlẹ si Man City.
Ọrọ naa da bi ere nigba ti abala kini bẹrẹ amọ bi nnkan ti ṣe n lọ ni Norwhich gbena woju Man City ti wọn si da goolu meji bo wọn.
Ohun to jẹ iyalẹnu ni pe awọn to kopa fun Norwhich kọ ni ojulowo awn agbabọọlu wọn nitori pe awn wn yẹn farapa.
Saaju ifẹsẹwọnsẹ yi ni akọnimọọgba Norwhich ti ni agbabọọlu ohun mẹwa lo farapa.
Bawo wa lawọn ''extra tire'' bi aṣa awọn kan ti ṣe wa na Man City? ni ibeere ti o gba ẹnu awọn eeyan loju opo ayelujara
Diẹ lara ohun ti awọn eeyan n sọ re.