Ewó ninu àwọn wọ̀nyí ni yóò wà níní ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù ààyò rẹ?

Ọ̀pọ̀ ìgbà ni a maa n ri awọn agbabọọlu ti a nifẹ si ṣugbọn ti wọn yoo wa ninu awọn ẹgbẹ agbabọọlu oriṣiriṣi.

Ti ẹ ba ni aanfani lati ko awọn ọmọ ẹgbẹ agbabọọlu ti yin jọ, ta ni yoo wa nibe?

Eyi ni anfani lati yan awọn ti ẹ fẹ sinu ẹgbẹ agbabọọlu aayo yin yii.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: