BBC GOV Debate: 'Tí ẹ bá yàn mi ní gómìnà Ogun, a ò ní rẹ̀yìn

Àkọlé fídíò, 'Gbogbo olùdíje Ogun fi dá àwọn ènìyàn lójú pé...'

Nibi ipade ifọrọwerọ BBC Yoruba laarin awọn oludije gomina ni ipinlẹ̀ Ogun, iroyin ko to afojuba. Lati ibẹrẹ titi dopin ni oriṣiriṣi ọrọ manigbagbe ti n jẹyọ.