Nkechi Blessing: Tí mo baá ṣe ǹkan tuntun, ẹ má bínú o, ẹ ò ní rí i
Òdú ni, kìí ṣàìmọ̀ fún olóko, mòlúmọ̀ọ́ká ni Nkechi Blessing báyìí nínú àwọn eré Yoruba. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọmọ Igbo pọ́ńbélé ni, ó ń fakọyọ ní gbogbo ìgbà pẹ̀lú àwọn akẹ́gbẹ́ rẹ̀ òṣèré.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: