LASTMA: Ẹ̀rí la nílò láti fi òsìsẹ́ tó ń gba rìbá jófin

Àkọlé fídíò, LASTMA: Ẹ̀rí la nílò láti fi òsìsẹ́ tó ń gba rìbá jófin

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni àìgbọ́raẹniyé máa ń sẹ́lẹ̀ láàrin àwọn òsìsẹ́ LASTMA níìlú Eko àtàwọn tó ń wa kẹ̀kẹ́ Márúwá.

Àwọn awakọ̀ Márúwá yìí tún ya bo ojú pópó láti tako owó kòtọ́ tí àwọn òsìsẹ́ Lastma ní àdúgbò Òjòdú-Berger ń gbà lọ́wọ́ wọn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: